Basic 7 Yoruba Third Term l2
Basic 7 Yoruba Third Term l2
L2
3. Ojo ninu ose ati Osu ninu Odun (days of the week and months of
the year)
4. Igba ati oju ojo bii igba ojo, igba eerun, igba oye, osan, ale, abbl
6. Owo kika: Orisii owo ile wa. Sise Iropo ati iyokuro fun owo.
9. Ayoka kukuru(Onisorogbesi)
11. IDANWO.
WEEK ONE (OSE KIN-IN-NI)
AGBEYEWO ISE SAA TO KOJA.
Igbelewon
Ko awon figo yii ni onka yoruba;
1.120=
2.135=
3.140=
4.145=
5.150=
6.125=
Ise Amurele
Ko awon onka yoruba yii ni figo;
1.Aarun-din-laadoje=
2.Ogofa=
3.Aadofa=
4.Eeji-din-logojo=
5.Aadojo=
ÌSE ASETILEWA
IGBELEWON
ISE ASETILEWA
1.Oruko awon eranko meloo ni a daruko ninu ayoka oke
yii?
2.Ta ni a la kunmo mo lori ninu ayoka yii?
3.Nibo ni isele yii ti sele?
4.Tani o n ba okere ja ninu itan oke yii?
5.Kin ni eko ti a ri ko ninu itan oke yii?
Ò̩ SÈ̩ KESAN (WEEK NINE)
TOPIC: ÒWE YORÙBÁ
Ò̩ rò̩ tí ó fi ìjìnlè̩ o̩ gbó̩ n àgbà àtijó̩ nípa ohunkóhun tí wó̩ n ti
ní ìrírí nípa rè̩ ni a ń pè ní òwe. Àwo̩ n àgbà àtijó̩ jé̩ o̩ ló̩ gbó̩ n àti
olóye púpò̩ . Wó̩ n maa ń s̩ e àkíyèsí ohun gbogbo tí O̩ lórun dá;
ènìyàn,igi,e̩ ranko àti gbogbo è̩ dá o̩ wó̩ O̩ lórun. Kí a tó lè pe
gbólóhùn ò̩ rò̩ kan ní òwe, ó gbó̩ dò̩ jé̩ ohun tó jé̩ òtító̩ nígbà
gbogbo, tí kìí tàsé rárá nípa ìrírí wo̩ n àtè̩ yìnwá.
Die ninu awon owe ti a ni niyi;
(i).Ò̩ nà kan kò wo̩ o̩ jà.
(ii).Àìlápá làdá ò mú.
(iii).Ogún o̩ mo̩ dé kìí s̩ eré fún ogún o̩ dún.
(iv).Dada ko le ja, sugbon o ni aburo to gboju.
(v).Bi aya ba mo oju oko tan alarinna a yeba.
(vi). Ba mi na omo mi ko denu olomo.
(vii). A kì í gbin àlùbó̩ sà kó hu è̩ fó̩ .
(viii). Ilá kìí ga ju onírè lo̩ .
(ix).Owo omode ko to pepe tagbalagba ko wo akeregbe.
(x).Lala to roke ile lo n bo.
ÌGBÉLÉWÒ̩ N
(i) Kí ni òwe?
(ii) Ohun tí a lè pè ní òwe ni ____
(a)ò̩ rò̩ tí a gbó̩ (b)ò̩ rò̩ geere(d)ò̩ rò̩ o̩ gbó̩ n tí ó fi ìrírí
hàn(e)ò̩ rò̩ -s̩ ókí.
ISE ASETILEWA
Parí àwo̩ n òwe wò̩ nyí:
(b) Ogún o̩ mo̩ dé_________
(c)Ò̩ gè̩ dè̩ dúdú kò yá bùsán___________
(d) Bí aya bá mojú o̩ ko̩ tán____________
Ò̩ SÈ̩ KÉ̩ WAA (WEEK TEN)
TOPIC: ÀYO̩ KÀ KÚKÚRÚ(ONÍSÒ̩ RÒ̩ GBÈSÌ)
ÌTÀKÚRÒ̩ SO̩
Tolú: Ayò̩ , bawo ni o se maa lo isimi re̩ ti o n bo̩ yii?
Ayò̩ : Mo n gbero lati lo si Kaduna lo̩ do̩ egbon iya mi Lolu
Tolú: O̩ pé̩ , iwo nko̩ ?
O̩ pé̩ : Mo fé̩ lo̩ si Enugu lo̩ do̩ egbo̩ n mi Kunle
Tolu: Ni temi, Eko ni o̩ do̩ àwo̩ n obi mi ni mo ti maa lo
Isimi temi.
O̩ pé̩ : Mo fe̩ fi akoko naa kawe fun idanwo JAMB ni.
Ayò̩ : Titi e̩ gbo̩ n mi ko ni lo si Kaduna nitori oun naa n
Kawe fun JAMB.
O̩ pé̩ : E̩ ko̩ nipa ise wo ni o n s̩ e ni University?
Ayò̩ : Dadii mi fe ki o lo̩ fun e̩ ko̩ Dokita, sugbon ise
Apoogun oyinbo ni o wu u.
Tolú: Ise ti emi paapaa ni ife̩ si ni ise Dokita
O̩ pé̩ : Ti emi naa ba ti yege idanwo NECO ti mo fe̩ s̩ e, ise̩
Lo̩ ya ni mo maa s̩ e.
Ayò̩ : Èmi ń lo̩ , ìpàdé di e̩ yin isinmi wa.
O̩ pé̩ & Tolú: Layo̩ ni a ó pade.
ÌGBÉLÉWÒ̩ N
(1) Ta ni o fe lo̩ lo isinmi rè̩ ní Kaduna?
A. Tolu
B. Ayò̩
D. O̩ pé̩
E. Olu
(2) Nibo ni O̩ pé̩ ti fe̩ lo̩ lo isinmi re̩ ?
A. Kaduna
B. Eko
D. Enugu
E. Ibadan
(3) Ta ni o fe̩ lo̩ fún e̩ ko̩ Ló̩ yà?
A. O̩ pe
B. Titi
D. Ayò
E. Tolú
ISE ASETILEWA
(i).Awon meloo ni a daruko ninu ayoka yii?
(ii)Ta ni o fe lo fun eko dokita?
(iii)Ta ni egbon Ope?
Ò̩ SÈ̩ KOKANLA (WEEK ELEVEN)
IDANWO (Examination)