0% found this document useful (0 votes)
73 views2 pages

Yoruba SS 3

The document is an examination paper for Ede Yoruba subject for SS 3 students at Mopem Nursery, Primary & College in Lagos. It contains a passage followed by multiple-choice questions and an essay prompt related to various themes and vocabulary in the Yoruba language. Students are required to answer questions based on the passage and write an essay on a selected topic.

Uploaded by

Adeniyi Adedeji
Copyright
© © All Rights Reserved
We take content rights seriously. If you suspect this is your content, claim it here.
Available Formats
Download as DOC, PDF, TXT or read online on Scribd
0% found this document useful (0 votes)
73 views2 pages

Yoruba SS 3

The document is an examination paper for Ede Yoruba subject for SS 3 students at Mopem Nursery, Primary & College in Lagos. It contains a passage followed by multiple-choice questions and an essay prompt related to various themes and vocabulary in the Yoruba language. Students are required to answer questions based on the passage and write an essay on a selected topic.

Uploaded by

Adeniyi Adedeji
Copyright
© © All Rights Reserved
We take content rights seriously. If you suspect this is your content, claim it here.
Available Formats
Download as DOC, PDF, TXT or read online on Scribd
You are on page 1/ 2

MOPEM NURSERY, PRIMARY & COLLEGE

26, Akinyemi Street, Off AdisaBalogun Street, Alapere-Ketu, Lagos.


SECOND TERM EXAMINATION
SUBJECT: EDE YORUBA CLASS: SS 3

AKAYE

Ka Ayoka Isale Yi, Ki O Si Dahun Awon Ibeere Ti Ote Lee.

Owo ti a da mo lo nkan ada leyin. Se Oladejo ti feran ise Ode ju, to bee ti eni kan ko le so boya inu
igbo ni o ngbe tabi ilu. Ni irole ojo kan, O pe Supo omokunrin re kan soso ti o bi pe ko niso loko
lati lo mu isu, o so pe oun naa nbo.

Supo mu igba. O gbona oko lo. Ni oju ona, Supo fe se gaa, kaka ki o wo inu igbo lo, ori igi ni o mu
gun lati lo yagbe..

Oladejo gber ni ile, o gbe ibon re ati apo ode re pelu ero lati wa eran igbe ti won yoo fi je iyan.

Asiko ti Supo nsokale lati ori igi ni Dejo de be, kini eyi? Obo ni tabi Ijimere orisii eranko ti o le je,
ni o wa si okan re sugbon ewo ni kii se obe ni o fi pari ero re.

Deji tan ina ran ilasa, gbo sa ti o gbo, ibosi oro o! lo tele e lati enu Supo. Supo subu lule, o na
gbalaja. Jebete gbe omo le Dejo lowo, o bere sii sun ekun ti ko baa mo.

IBEERE

1. Kini ero Dejo ni pa ‘ewo ni kii se obe’ ki o 9. Ninu “emi iba lo sugbon ko si owo”
sa ti pa (a) Eran yoo wu ti ise (b) Ijimere Sugbon je (a) Oro aponle (b) Oro Asopo
(d)Obo (e) Obo tabi Ijimere (d) Oror atokun (e) Oro eyan
2. Kin ni o se iku pa Supo? (a) Aigboran (b) 10. Oro ise ninu “Funk eta eran nla” ni (a)
Are kare (d) Baba re (e) Omugo Funke (b) Eran (d) Ta (e) Nla
3. “Se gaa” ninu ayoka yi tumo si (a) Gun igi 11. “Nla” ninu “FUNKE tae ran Nla” je
(b) Yagbe (d) Peran (e) Sere apeere or (a) Apejuwe (b) Apole (d) Oruko
4. “Owo ti ada mo lo nkan ada leyin tumo si (e) Ise
(a) Ise ti ada mo se lo nkan ada leyin (b) 12. “Yemi ti sun fonfon nigbati mo de “fonfon”
Ise sise ada lo npa ada (d) Ohun ti a ba je (a) Oro apejuwe (b) Oro aponle (d) oro
mo se ju lo nko ba ni (e) Ounje ti a ba je lo atokun (e) oro asopo
nko ba ni 13. “Yala e lo soja tabi e ko lo soja e o jiya”
5. Ki ni Ilasa tumo si (a)Aara (b) Agogo (d) oro asopo ti o wa ninu gbolohun yi ni (a)
Ibin (e) fere e, o (b) e, lo (d) lo, tabi (e) Yala, tabi
6. A maa ri gbolohun “ipade wa bi oyin” ninu 14. Oro oruko ti o wa ninu gbolohun “Emi ni
aroko yi (a) Alalye (b) Onileta (d) Asotan mo ran an” ni (a) Emi , ni (b) ni, m (d) mo,
(e)Asariyanjiyan ran (e) Mo, an
7. Leta gbefe nil eta si (a) Alejo (b) Arabinrin 15. Oror afarajoruko ni (a) emi, awon, a (b)
(d) Oga Ile ise (e) Olootu emi , awon, oun (d) eyin, oun, iwo
8. Ori oro to je mo aroko asapejuwe jule ni 16. Isori oro ti ose dandan, lati wa ninu
(a) Ija olopaa ati awon akeeko ijeta (b) Ile gbolohun ni (a) Oro apejuwe (b) Oro
Iwe mi (d) Riba (e) Owo Koko aropo oruko (d) oro ise (d) oro oruko
17. Iparoje je yo ninu (a) Alakaa (b) Aroorun 28. Faweli pin si ona ____ (a) meji (b) meta
(d) eleja (e) Ileewe (d) merin
18. Igbese fonoloji wo lo mu “dara” di “daa” 29. Iro ______ naa ni a mo si toniimu (a) faweli
(b) konsonanti (d) ohun
(a) ankoo faweli (b) Aranmo (d) Iparoje (e)
30. Eda foniimu konsonanti ni _______ (a) / b/
iyopo faweli ati / d/ (b) /i/ ati m (d) /I/ ati / n/
19. Yinka can not do without taking her 31. Idako ‘on’ ni _____ (a) / on / (b) /c/ (d) / ‫כ‬
breakfast tumo si (a) Yinka feran ounje 32. Awon Iserun eni tumo si (a) Baba-nla eni
aro (b) Yinka ko le se lai je ounje aaro (d) (b) eni ti o se iran eni sile (d) eni to na
Yinka feran ounje aaro jije (e) Yinka ko le omokunrin ile
se ko ma jeun 33. Inu _______ ni a ti n gbo nipa oniruuru
oruko idile (a) oriki orile (b) iwure (d) ofo
20. Itumo “Health is wealth” ni (a) Alafia
34. Ojubo iserun eni le wa ni _____ ati (a) Inui
atooro Ogbogba ni (b) Alafia tayo (d) Ilera le (b)agboole (d) ilu odikeji
loro (d) Alafia toro 35. Ona _____________ ni a le gba ya oro lo
21. ”The cat was let out of the bag” tumo si ninu ed Yoruba (a) meji (b) meta (d)
(a) Asiri tu (b) Epa ko boro mo (d) Ologbo merin
naa ti kuro ninu baagi (e) Won tit u 36. Awon ____ ni won maa n ku pelu Oba laye
Ologbo naa kuro ninu baagi atijo ki o ba le ri won ran nise ni ile
ibomiran ti o ba ja si. (a) Abobaku (b)
22. ………ni ege oro ti eni lo gba jade
eru (d) ara ile oba
leekansoso (a) oro (b) apola (d) silebu
37. _________ni a n pe eni ti o ti ku, ti o tun lo
23. ………..ni a n lo fun idagbasoke ilu. (a) iro
si ile ibomiran (a) ayorunbo (b) Akudaaya
(b) egbe (d) aaro.
(d) eni irapada
24. …………ni maa n gbo ju ninu silebu. (a)
38. _____ ni opomulero fun gbolohun (a) oro-
odo silebu (b) ihun silebu (d) apaala
oruko (b) oro-ise (d) eyan
silebu.
39. Awon wo lo maa n lo laali ju? (a) obinrin
25. …… ki i se ara erongba elegbejegbe. (a)
(b) okunrin (d) omode (e) arugbo
ona yiye (b) afara tite (d) aibowofagba.
40. Idi ti won fi maa n korin nibi ikomojade ati
26. Apeere elegbejegbe laye atijo ni ………. (a)
igbeyawo ni _________ (a) ounje jije (b)
egbe onimototo (b) egbe ogboni (d)
nitori ilu lilu ti o wa nibe (d) nitori a ki i
Rotary
saba korin lojoojumo (e) inu didun
27. Foniimu ni _______ (a) iro ti a pe (b) to le
fi iyato han (d) iro ti o dun

APA KEJI
DAHUN IBEERE META NI ABALA YI, SUGBON IBEERE AKOKO SE PATAKI.
1. Ko aroko ti ko din ni ota-leni-odunrun eyo oro lori okan ninu awon koko wonyii.
a. Ogba ile eko mi
b. Ijamba kan ti o soju mi
c. Ipa ti ero alatagba nko lawujo wa
d. Ko leta si egbon re kan ti o wa ni orile ede miran lori bi ise olopa ti ri ni orile ede
Naijiria
2. Ko gbolohun merin, ki o si fa ila si oro aponle inu won
b. Kin ni oro aponle?

You might also like